http://peakradio.net/wp-content/uploads/2020/07/Iwosan-ni-Ilana-Ibile.mp3 Awon baba so pe Kagbado to daye nkan ni adie nje, Ki isu to diyan agunsu lodo, Ki agbado to di Eko aloo papo. Nigba aye awon baba wa ona kan langba se iwosan aisan lorisiris ko to di pe toyinbo de.